Ìwé Imùlɛ̀ tètè an

Lɛ́kpasɛ̀ ìwé Ìmùlɛ̀ Tètè an ɔ́, àá ti tú ìwé Ìkpìlɛ̀ ayé, ìwé Rùútù, ìwé Jonásì, ìwé Neemíì kánná ìwé Ɛsidrásì. Iín ɛ yɔ́ɔ gbà án si líìtá ɛ̀rɔ ín líbibí.

Partager